Home Posts tagged Ambassador Zubairu Dada
Yoruba
Alákoso kejì fọ́rọ̀ ilẹ̀ òkèrè Ambassador Zubairu Dada, ti pè fún ìbásepọ̀ tó gbúmọ̀ láarin gbogbo àwọn lájọ-lájọ àti ẹ̀ka tó wà lábẹ́ ìsàkóso ọ̀rọ̀ nípa ilẹ̀ òkèrè. Ó sọ̀rọ̀ yí nílu Abuja, lásìkò tón gba àwọn ìgbìmọ̀ aláse ẹ̀ka àtò gbogbo nílẹ̀ adúláwọ̀ lálejò ní ófìsì rẹ̀. Alákoso kejì fọ́rọ̀ ilẹ̀ òkèrè, Ambassador Dada […]Read More...
Load More