Home Posts tagged Bayelsa
Yoruba

Ati wọlé sílé ẹ̀kọ́ ìmọ̀ nọ́ọ̀si: Iléesẹ́ olóògun òfurufú sèkìlọ̀ fáràlú nítorí àwọn oníjìbìtì

Iléèsẹ́ olóogun ofurufu ilẹ̀ yí ti sèkìlọ̀ fáwọn ọmọ orílẹ̀èdè yí tó n lépa àti wọlé sílé ẹ̀kọ́ gíga ìmọ̀ nọ́ọ̀si pé kí wọ́n sọ́ra kí wọn ma báà bọ́ sọ́wọ́ àwọn oníjìbìtì. Ìkìlọ̀ yí ló wáyé nípa ayédèrú ìwé ìgbaniwọlé sílé ẹ̀kọ́ náà tó ń lọ káàkiri orí ẹ̀rọ ayélujára. Olùdarí ètò ìròyìn ọ̀hún […]Continue Reading