Home Posts tagged Dapo Abiodun
Education
Ogun State Governor, Prince Dapo Abiodun says his administration would reconstruct all access roads within and outside tertiary institutions across the state. The Governor made this known while playing host to members of National Association of Nigerian Students, NANS, and National Association of Ogun State Students, NAOSS, in his Oke-Mosan Abeokuta office. Governor Read More...
Yoruba
Ìgbaniwọlé sáwọn ilé ìwé ibití àwọn akẹ́kọ tí ńgbénú ọgbà ilé ẹ̀kọ́ taládaní nípinlẹ̀ Ògùn ni yio sinmi lé ìpinu àwọn alásẹ ilé ìwé àti ẹgbẹ́ àwọn òbí àti olùkọ́. Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn, ọmọba Dapọ Abiọdun ló sọ̀rọ̀ yí nígbàtí ó ńkede pé àyẹ̀wò àrùn covid-19 fún àwọn akẹ́kọ nípele ẹ̀kọ́ oníwe mẹ́wa tó ńgbé […]Read More...
Judiciary
Seventy-five coronet Obas sacked by the Ogun State Government have challenged their demotion before the state High Court sitting in Abeokuta. The court presided over by Justice Akinyemi in the inaugural sitting on the interlocutory injunction filed by the coronet Obas ruled that the status quo should be maintained. Justice Akinyemi explained that the relationship that Read More...
Yoruba
Gómìnà Babajide Sanwo-Olu gbàwọn ọmọ orílẹ̀dè yíì níyànjú láti nígbàgbọ́ kíwọ́n sì fìmọ̀sọkan, pé ilẹ̀ yíì sì máà dára. Gómìnà Sanwo-Olu tún kọminú lórí báwọn ọmọ orílẹ̀dè yíì kan se ńsíkúrò nílẹ̀ yíì, lọ sí ilẹ̀ òkèrè níbi tílẹ̀ tó ń mú kílẹ̀ Nàijírìa pàdánù àwọn ọlọ́pọlọ pípé ẹ̀dá, tíwọ́n lè mú ìdàgbàsókò bá orílẹ̀dè. […]Read More...
Load More