Home Posts tagged Enviromental Pollution
Yoruba

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ogun ti ilé isẹ méjìlá pa fún biba àyíká jẹ

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ogun ti gbé àwọn ilé isẹ méjìlá kan tipa lágbègbè Ogijo ńipinle náà, nítorí titipa sofin atìlànà toromo biba àyíká jẹ. Alákoso foro àyíká ńipinle náà, ogbeni Abiodun Abudu-Balogun tó lé waju ìkórè nidi ètò itopinpin náà, ṣàlàyé pé, àwọn gbé àwọn ilé isẹ náà tipa nítorí báwọn nkan ti pèsè bayika dọ́gba, […]Continue Reading