Gomina ipinle Oyo, Onimo Ero Seyi Makinde ti salaye igbiyanju eto isakoso ijoba re lori ati koju ipenija eto aabo nipinle naa. Gomina Makinde se adayanri oro yi lasiko to n gbalejo asoju awon logaloga ileese olodun to lo fun eto idanileko eleekerinlelogoji ile eko oloogun to wa ni Jaji labe Continue Reading
Ileese olopa ile yi ti tepele mo igbiyanju lori ipese aabo to peye fawon ileese ati olori jori ton se amulo opopona marose Ibadan silu Eko. Igbakeji oga agba ileese, Olopa ile yi fun ekun keji, Ogbeni Johnson Kokumo lo fowo oro yi soya nilu Abeokuta lasiko abewo lenu ise to se si Gomina ipinle Ogun, […]Continue Reading
Àrẹ Muhammade Buhari ti sọ pé àmúgbòrò yo de bá ìgbáyé gbádùn àwọn èyàn nílẹ̀ Nàijírìa, bẹ̀rẹ̀ nípa ìpèsè ètò àbò tó múnádóko. Nílu Maiduguri, l’afin Shehu ti Borno, ni àrẹ ti sọ̀rọ̀ ìdánilójú yi . Àrẹ ẹni tó ń se àbẹ̀wò ẹnu isẹ́ ọlọ́jọ́ kan sípinlẹ̀ Borno, ló ti kọ́kọ́ se ìpàdé pọ̀ pẹ̀lú […]Continue Reading