Home Posts tagged Ètò Ọ̀gbìn
Yoruba

Ilé ìfowópamọ́ ìdàgbàsókè ilẹ̀ adúláwọ̀ késíjọba láti mọ́rọ̀ ìdàgbàsókè ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn lọ́kunkúndùn

Ilé ìfowópamọ́ tón r;is;i ìdàgbàsókè ilẹ̀ adúláwọ̀, AFDB, àti àjọ tón rí sétò ìsúná ìdàgbàsókè ẹ̀ka ètò ọ̀gbìn nílẹ̀ òkèrè, IFAD, ti mú ìpínlẹ̀ Ògùn gẹ́gẹ́ bí ibití àkànse ètò ọ̀gbìn kan tíwọ́n sàgbékalẹ̀ yóò ti wáyé. Olùdarí àjọ IFAD, nílẹ̀ yíì, ọ̀mọ̀wé Patrick Habamenshi ló sọ̀rọ̀ yíì di Continue Reading
News Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Ńgbèrò Láti Gba Àwọn Akẹ́kọ Jáde Nílé Ẹ̀kọ́ Gíga Sẹ́nu Isẹ́ Lẹ́ka Ètò Ọ̀gbìn

Ìjọba àpapọ̀ ti setán láti gba àwọn akẹ́kọ jáde, ilé ẹ̀kọ́ gíga ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n níye sẹ́nu isẹ́ lẹ́ka ètò ọ̀gbìn láti sàtìlẹyìn fáwọn àgbẹ̀ yíká orílẹ̀ èdè yí. Akọ̀wé àgbà, fún ẹgbẹ́ tón mójútó ètò ọ̀gbìn àti ìdàgbàsókè ilẹ̀, ọ̀gbẹ́ni Paul Ikonne ló sọ̀rọ̀ yí fáwọn akọ̀rìnyìn nílu Abuja pẹ̀lú àlàyé pé àwọn akẹ́kọ […]Continue Reading