Home Posts tagged Head of Service
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ ti pàsẹ fáwọn àjọ aláabo, láti fàsẹ kónílé ógbélé múlẹ̀ fáwọn òsìsẹ́

Ìjọba àpapọ̀ ti pàsẹ fáwọn àjọ aláàbo tó wà láwọn ẹnu ìloro àwọn ilé-isẹ́ ìjọba látiridájú pé, àwọn òsìsẹ́ ìjọba tó wà lákàsọ̀ kẹtàlá sókè niwọn gba láàye láti wọ àyíká àwọn ilé-isẹ́ ọ̀hún. Èyí ló wáyé nípasẹ̀ àsẹ tígbìmọ̀ amúsẹ́yá ilé isẹ́ àarẹ lórí covid 19, pé káwọn òsìsẹ́ tó wà lákàsọ̀ kejìlá sísàlẹ̀ […]Continue Reading
Politics

Ogun Gets New Head of Service

A new Head of Service has been appointed for Ogun State. She is Alhaja Selimot Olapeju Ottun, replacing the former Head of service Mrs Amope Ajibola Chokor, who bowed out of the state public service last weekend. In a statement by the Chief Press Secretary to the Governor, Mr Kunle Somorin, Governor Abiodun describes the new […]Continue Reading