-
Igbimo Olubadan Seleri Lati Se Agbelaruge Fun Ona Atijo Ti Won N gba D’ade
Igbimo Olubadan to fenuko lati maa jee Oloye agba dipo Oba Alayeluwa. Nigba to n baa won akoroyin soro leyin ipade to waye ni afin Ojaba ti Olubadan ile, Ibadan, Oloye Tajudeen Ajibola so pea won gba igbese gomina lori ipinu re lati da awon pada sori jije Oloye agba. Lori oro to si w…