Àwọn mẹ́tàlá ni wọ́n gbẹ́mi min tí àwọn méjìlá min sí farapa nínú ìjàmbá ọkọ̀ tó wáyé lópopónà másọsẹ̀ ìbàdàn sí Èkó. Gẹ́gẹ́bí ohuntí ìròyìn wí, ìsẹ̀lẹ̀ náà ló wáyé láàrin ọkọ̀ èrò tó ńrìnrìn àjò bọ̀ láti ìlú Èkó àti ọkọ̀ akẹ́rù tó wáyé lójú kan níwájú ilé isẹ́ tó ńse ohunti wọ́n fi […]Continue Reading
Nise ni oko-akero tegbe agbaboolu Wikky Tourist jona furu-gurru, ninu ijamba oko to waye lopopona Kibboo, nilu Jos nipinle Platu. Egbe agbaboolu ohun to fi ilu Bauchi se ibujoko, lowa loju ona re silu Wuyo, nipinle AkwaIbom, fun ifesewonse pelu egbe agbaboolu Dakkada. Gege bi iroyin se wii, ebge agbaboolu oohun lokuro ni ibugbe won […]Continue Reading