Home Posts tagged Ijoba Ipinle Oyo
Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ láti sisẹ́ tọ ìpèsè ilégbe ọ̀tàalélọdúnrún láipẹ

Ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ sọpé láipẹ àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ yóò ma jànfàní ilé-tóworẹ̀ ògajaralọ nípasẹ̀ okòòwò pẹ̀lú ìjọba àti aládani láipẹ. Alága, àjọ tó ńrísí ilé-ìgbé nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, olóyè Bayọ Lawal sọ èyí lásìkò tó ńkopa lórí ètò ilésẹ́ Premier F.M lédè gẹ́ẹ̀si Straight Talk. Olóyè Lawal sàlàyé pé, ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti ńsisẹ́ tọ́ọ̀ […]Continue Reading