Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin kejì, ọ̀gbẹ́ni Fẹmi gbajabiamila ti rọ àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ lẹ́ka afẹ́fẹ́, Gas láti sisẹ́ papọ̀ pẹ̀lù ìjọba fún ìdàgbàsókè ẹ̀ka ọ̀hún, lọ́nà àtijẹ́ kò so èso rere.

Ọgbẹni Gbajabiamila ló gbọrọ àmọ̀ràn yíì kalẹ̀ lákokò ikọ̀ asojú kan látile se tón ri sọ́rọ̀ afẹ́fẹ́ Gas nílẹ̀ yíì lálejò lófìsì rẹ̀, nílu Abuja.

Ó tọ́kasi pé àwọn ẹ̀ka tón rí sọ́rọ̀ afẹ́fẹ́ gási nílesẹ́ elépo rọ̀bì ilẹ̀ yíì náà ńkó ipa pàtàkì lẹ̀ka ètò ọrọ ajé orílẹ̀èdè yíì, pẹ̀lú bíwọ́n se rogbokule epo rọ̀bì nìkan.

Adarí ilé asòfin kejì náà, kò sài fikun pé, àbá òfin tóníse pẹ̀lú ilé-isẹ́ epo bẹtirolu tise ńlọ lọ́wọ́ lórí rẹ̀, ti pàsẹ àwọn ànfàní tóyẹ silé fáwọn akọ́skmọsẹ́ lẹ́ka epo rọ̀bì láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú ilé asòfin náà fáseyọrí ẹ̀ka náà lọ́jọ́ iwájú.

Aminat/Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *