Home Posts tagged ìpínlẹ̀ Ògùn
Yoruba

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn sèlérí láti ma din owó osù àwọn òsìsẹ́ rẹ̀ kù

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn, ọmọba Dapọ Abiọdun ti fọwọ́ ìdánilójú sọ̀yà pé òun kò ní dín owó osù àwọn òsìsẹ́ kù, pẹ̀lú ìpèníjà tón dojúkọ ètò ọrọ ajé nílẹ̀ yí. Gómìnà Abiọdun sọ̀rọ̀ ìdánilójú yi nílu Abẹokuta lásìkò tón sínu pẹ̀lú àwọn olórí ẹgbẹ́ òsèlú All Progressive Congress APC, nílu Abẹokuta. Óní Continue Reading
News Yoruba

Ìpínlẹ̀ Ògùn Fọwọ́ Òfin Mú Olùgbé Àdọ́ta Lórí Ẹ̀sùn Pé Wọ́n Tàpá Sófin Tó De Ìtànkálẹ̀ Àrùn Covid-19

Kòdín ní àwọn olùgbé ìlú Abẹokuta tó jẹ́ àdọ́ta níye tí wọ́n ti fún ní ìjìyà láti sisẹ́-ìlú fún ọjọ́ méjì lẹ́yìn tí wọ́n jẹ̀bi níwájú ilé ẹjọ́ alágbeká pàtàkì ti ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn gbé kalẹ̀ lórí fífi ẹsẹ̀ òfin dídènà covid 19, múlẹ̀, èyí tón pọ̀si lẹ́nu lọ́lọ́ọ́ yi. Ìgbìmọ̀ tón fi ẹsẹ̀ òfin […]Continue Reading
Yoruba

Ijọba ìpínlẹ̀ Ògùn sèlérí láti sàmúlò ìmọ̀ ẹ̀rọ, kagbega lè débá ìlànà ètò ẹ̀kọ́

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn ti sọ pàtàkì lílo ìmọ̀ ẹ̀rọ láti fi kọ́ni láti mú kí àgbéga dé bá ẹ̀ka ètò níbamu pẹ̀lú bí wọ́n tínse láwọn orílẹ̀ èdè tó ti gòkè àgbà. Olùdámọ́ran sí Gómìnà ìpínll Ògùn lórí ètò ẹ̀kọ iléwe alákọbẹ̀rẹ̀ àti girama Arábìnrin Ronkẹ Soyọmbọ, ló sọ̀rọ̀ yí níbi àpérò kan tó wáyé, […]Continue Reading