Home Posts tagged Mr Oluwole Olusegun
Yoruba

Ọdún Àjínde: Àjọ NSCDC Kó Àwọn Òsìsẹ́ Rẹ̀ Tó Lé Lẹ́gbẹ̀rún Méjì Síta

Àjọ ààbò ara ẹni láàbò ìlú, NSCDC, nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti kó àwọn òsìsẹ́ rẹ̀ tó tó ẹgbẹ̀rún méjì àbọ̀ ló si tibu tóòro ìpínlẹ̀ yi láti ríì dájú pé kò sí àayè fún ìwà ọ̀daràn lásìkò pọ̀pọ̀sìnsìn ọdún ajinde. Àtẹ̀jáde ti agbẹnusọ àjọ náà nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ọ̀gbẹ́ni Oluwọle Olusẹgun fi síta nílu Ìbàdàn sọ wípé […]Continue Reading