Home Posts tagged Òndó
Yoruba

Ọwọ́ ilésẹ́ ọlọ́pa tẹ àwọn tí wọ́n furasí pé wọ́n jẹ́ jàndùkú olósèlú nípìnlẹ̀ Òndó

Ilé ẹjọ́ magistrate nílu Àkúrẹ́ ti fi àwọn ẹni tí wan furasí pé, wọ́n jẹ́ jàndùkú olósèlú méje, tọ́wọ́tẹ̀ lọ́sẹ̀ tó kọjá pẹ̀lú àwọn on ìjà lọ́wọ́ níjọiba ìbílẹ̀ ose nípinlẹ̀ náà sọ́gbà ẹ̀wọ̀n tó wà ní Olokuta nílu Àkúrẹ́. Àwọn ẹni tí wọ́n furasí méje yi, lọ́wọ́ àwọn agbófinró tẹ̀ lọ́jọ́ Continue Reading