Home Posts tagged The Polytechnic Ibadan
Yoruba

Aláṣẹ Ilé Ẹ̀kọ́ Poly Ìbàdàn Bẹ̀rẹ̀ Ìjíròrò Láti Yanjú Ìyansẹ́lódì

Àwọn aláṣẹ ilé ẹ̀kọ́ gbogbonise Ìbàdàn tí bẹ̀rẹ̀ síní jiroro pẹ̀lú àwọn ádárì ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ ilé ẹ̀kọ́ náà pẹ̀lú ìrètí láti tètè yanjú ìyansẹ́lódì tó ń lọ lọ́wọ́. Níbi ìpàdé tí Alága Ìgbìmò Aláṣẹ ilé ẹ̀kọ́ náà, Ọ̀jọ̀gbọ́n Kúnlé Akínyemí darí ni àwọn ọmọ ìgbìmò mẹ́tèeta yoku pé ṣe si àti àwọn aláṣẹ ilé […]Continue Reading