Yoruba

Gómìnà Sanwoolu gbàmọ̀ràn lórí ìfọkànsì

Gómìnà Babajide Sanwo-Olu gbàwọn ọmọ orílẹ̀dè yíì níyànjú láti nígbàgbọ́ kíwọ́n sì fìmọ̀sọkan, pé ilẹ̀ yíì sì máà dára.

Gómìnà Sanwo-Olu tún kọminú lórí báwọn ọmọ orílẹ̀dè yíì kan se ńsíkúrò nílẹ̀ yíì, lọ sí ilẹ̀ òkèrè níbi tílẹ̀ tó ń mú kílẹ̀ Nàijírìa pàdánù àwọn ọlọ́pọlọ pípé ẹ̀dá, tíwọ́n lè mú ìdàgbàsókò bá orílẹ̀dè.

Ó wá gbàwọn ọmọ ilẹ̀ yíì nímọ̀ràn, papa jùlọ àwọn ọ̀dọ́ láti túbọ̀ lẹ́mi ìfọkànsì, kíwọ́n sìridájú pé àwọn ń kópa tíwọ́n náà, sílé síwájú àtàgbéga ilẹ̀ Nàijírìa.

Kẹmi Ogunkọla/Mosọpẹ Kẹhinde

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *