Yoruba

Ilé ẹjọ́ tó gajù ti da ẹjọ́ ẹgbẹ́ òsèlú PDP tí ó tako ìjáwé olúborí

Ilé ẹjọ́ tó gajù ti da ẹjọ́ òsèlú PDP, àti olùdíje fún ipò àarẹ Atiku Abubakar nù, fún títako ìjáwé olúborí àarẹ Muhammadu Buhar i nínú ètò ìdìbò èyí tí ó wáyé nínú osù kejì ọdún 2019.

Atiku àti ẹgbẹ́ òsèlú rẹ̀ tako ìdájọ́ tí onídajọ́ Mohammed Garba gbékalẹ̀ láti fi ìjáwé olúborí àarẹ Muhammadu Buhari múlẹ̀.

Ìjóko ẹni méje tí ilé ẹjọ́ gíga èyí tí onídajọ́ àgbà Tanko Muhammed darí, ni ó wọ́ igi lé ẹjọ́ Atiku àti ẹgbẹ́ òsèlú rẹ̀.

Kẹmi Ogunkọla/Damilọla

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *