Yoruba

Ile igbimo asofin daba afikun isinmi leyin ibimo fawon osise ijoba

Asofin kan nile igbimo asofin ti ipinle oyo, Arabinrin Bimbo Oladeji feki ijoba ipinle oyo satungbeyewo isinmi leyin ibimo fun awon osise ijoba nipa siso di osu mefa dipo osu merin to wa tele.

Nigbati on gbe aba naa kale, Arabinrin Oladeji nisiasfikun isnmi leyin ibimo je ona kan lati dena ati din iku awon omo ikoko ati iyalomo ku nipinle yi.

Asofin naa toka si wipe ilana lori isinmi leyin ibimo ti won samulo re nipinle yi ko wa ni ibamu pelu eyi ti ajo eleto ilera lagbaye , w.h.o. la kale.

Nigbati on fesi, Adari Ile Igbimo Asofin, Ogbeni Adebo Ogundoyin wa kesi igbimo teekoto ile lori oro awon obinrin ati igbayegbadun lati sise po pelu ile ise ijoba foro awon obinrin lati lee sagbekale aba to ba ye lori oro naa. Yemisi Dada/Mosope Kehinde

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *