Home Posts tagged OYHA
Yoruba
Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ yóò sàyẹ̀wò fáwọn òsìsẹ́ àjọ elétò ìdìbò ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, OYSIẸC, gẹ́gẹ́ bí ètò ìgbaradì fún ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ tí yóò wáyé láipẹ. Gómìnà Seyi Makinde forúkọ àwọn osojú àjọ OYSIẸC náà sọwọ́ síì ilé, tí ósì jẹ́ kíkà fún ilé nípasẹ̀ adarí ilé, ọ̀gbẹ́ni Adebọ Ogundoyin. Orúkọ àwọn mẹ́jọ tí […]Read More...
Education
Legislators in the Oyo State House of Assembly, OYHA, want Governor Seyi Makinde to urgently consider the overhauling of the seven technical colleges across the state to make them run effectively. This followed a motion on the need to improve technical and vocational education to enhance youth empowerment, brought to the House by a member […]Read More...
Yoruba
Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti sèlérí láti tẹ̀tíwájú nínu sísa ipá rẹ̀ lórí dídábòbò ètò àwọn ọmọbíbí ìpínlẹ̀ yí nípasẹ̀ gbígbé òfin tí yo mú kígbàdẹrùn fáràlú kalẹ. Alága ìgbìmọ̀ tón rírí ọ̀rọ̀ ilẹ̀ òkèrè nílé asòfin, ọ̀gbẹ́ni Seyi Adisa ló sèlérí yi lásìkò tón kópa lórí ètò ilésẹ́ Premier FM tí wọ́n pè […]Read More...
Politics
Members of the Oyo State House of Assembly, OYHA, have eulogised the immediate past governor of Oyo State, Senator Abiola Ajimobi, describing him as man with unprecedented achievements who lived a fulfilled life and solidified his impact in the history of Oyo state. At a special plenary in honour of the late governor, the lawmakers, […]Read More...
Load More