Yoruba

Ijoba Apapo Jeje Ipese Abere Ajesara Covid-19 Titi Ipari Osu Yi

Ijoba apapo yio nilo owo toto trillion meji naira lati fun awon omo ile yi toto million kan labere ajesara covid-19

Oga agba ajo to nrisi ori ile iwosan alaabode nile yi, Dokita Faisal Shuaib lo soro yi di mimo nibi ipade oniroyin  ti igbimo amuseya ijoba apapo lori covid-19 se nilu Abuja.

Dokita Shuaib ni abere ajesara eyiti Pfizer Biontech si toto egberun lona ogorun kan ni ile yi yio gba nipari osu yi.

O tun ni won yio ri abere ajesara ofe toto million mejilelogoji gba leyiti o ni ninu gbogbo oniruru awon abere ajesara ti won ti buwolu to de wa loja bayi.

Gegebi o se wi, million mejilelogoji awon abere ajesata wonyi ni yio to fun ida ogun awon omo ile yi ni won to million lona igba ati mefa.

Dokita Shuaib fikun wipe igbimo amuseya ijoba apapo lori covid-19 ati ile ise ijoba apapo foro ilera ti nsise lori wiwa owo lati ra abere ajesara sii.

Net/Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *