News Yoruba

Ijoba Apapo Yo Mu Didokowo Lori Nkan Osin Lokunkundun Lati Mu Agbega De Ba Eto Oro Aje

Ijoba apapo ti sope didokowo leka nkan osun nile Naijiria lo le mu ki owo toto million lona metalelogbon ko kun agbega eto oro aje nile yi.

Alakoso feka eto ogbin at idagbasoke igberiko Sabo Nanono lo je koro yi di mimo fawon akoroyin nilu Abuja, pelu atokasi pe ijoba apapo hin sise kara lati le gbaruku tie ka yi fun agbega eto oro aje.

Oni erongba ijoba apapo lati pin eto oro aje si yeleyele, kuro nidi epo roobi nikan soso, yo bere sinu soo.

Ogbeni Nanono sope, lati wa mu keto naa yori sir ere, ilese naa ti bere sini samulo awon ona igbalode tie ka eto ogbin yo fi tunbo rugogo si.

Banjo/Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *