News Yoruba

Gomina Ipinle Ekiti Fidi Gbigbe Awon Ti Won Furasi Pe O Demi Eeyan Meji Legbodo Mule

Gomina Ipinle Ekiti, Omowe Kayode Fayemi fidi re mule pe owo tit e awon ti won funra sii pe won wa nidi rogbodiyan to yori si iku awon meji ni Omuo-Ekiti lasiko idibo lati di alafo to si sile ni ekun idibo ila oorun Ekiti nile igbimo asofin ipinle Ekiti.

Gomina kede oro yi lasiko to lo sabewo e ku ara feraku si aafin Olomuo ti Omuo-Ekiti, Oba Noah Ominigbehin nilu Omuo Ekiti.

Omowe Fayemi wa fid a awon eniyan Ipinle Ekiti loju wipe, awon ti won funra si ohun ni won yio foju won wina ofin, to wa fikun wipe awon towoba naa ni won yio foju won ba ile ejo loni lori esun ipaniyan.

Gomina eniti o tun sabewo sibiti isele naa ti waye tun sabewo sawon molebi awon oloogbe to wa seleri ati seranwo fun won.

 Ogunrinde/Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *