Alága ìgbìmọ̀ tón mójútó ọ̀rọ̀ ìrìnà ọkọ̀ òfurufú nílé asòfin, ọ̀gbẹ́ni Nolim Nnaji ńfkkí wan se àfikún owónà fún àwọn ilésẹ́ ọkọ̀ òfurufú, kí wọ́n lè lánfání láti kápá báwọn èyàn tó fk lo ojú òfurufú fi rìnrìnàjò, sen pọ̀si.

Ó sọ̀rọ̀ yí lásìkò ìjírórò pọ pẹ̀lú ìgbìmọ̀ àti àwọn olórí lẹ́ka ilésẹ́ yi èyí tí akọ̀wé àgbà, fún ẹ̀ka ọkọ̀ òfurufú, onímọ̀ ẹ̀rọ Hassan Musa léwájú rẹ̀.

Ọgbẹni Nneji sinfẹ kí wọ́n fọwọ́ ìdánilójú sọ̀yà lórí fífi àbò tó péye múlẹ̀ lórí ìrìnàjò òfurufú. Tó sín ńfẹ́ kí àkọlé àbò tó ti wa láti àimọye ọdún sẹ́yìn tlsíwájú.

Ilé asòfin wá palasẹ fún ìgbìmọ̀ yi láti pe àwọn ilésẹ́ ọkọ̀ òfurufú láti sàlàyé on tó sokùnfà jijalulẹ ọkọ̀ òfurufú méjì tó sẹlẹ̀ láipẹ yi, láti lé fòpín sírúfẹ́ ìsẹ̀lẹ̀ yi lọ́jọ́ iwájú.

Net/Afọnja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *