Lameeto awujo, Ogbeni Henry Odeh ti tenumo idi to fi yen ki atunto o waye lagbo oselu ati eto oro aje orileede yii.

Ogbeni Odeh foju oro yi lede lasiko to n kopa lori eto Straight Talk lede gegebi nileese wa Premiers fun.

Lameeto awujo naa salaye wipe o se Pataki fun ile Nigeria lati seto ijoba tooto nibi ti ipinle yio ti ni agbara lati eto akoso ijoba bi ti to ati no ti yen lagbegbe won.

Ogbeni Odeh tun parowo si gbogbo omo ile yip e ki won gba Alafia ati isokan laaye, bee lo tun ro won pe ki won maa tele liana to ye nipa yoowu ti won ba fe kijoba gbo aroye won.

 Net/Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *