News Yoruba

Àwon Ojà Àgbò Ti ñ Se Wòtù Wòtù Pèlú Bódún Iléyá Se Ku Òsè Kan

Pelu bi ó se ku òsè kan kí odún iléyá wolédé, òpò àwon agbègbè àtawon ojà ti won ti nta àgbò ni ó ti n se wotù wotù ferò bayii.

Akòròyìn ilé-isé wa to sàbèwò sí agbègbè Aléshinlóyé sí Jéríchò jábò wípé okò akérù nlá tó kó Eran àgbò àti màálù wá láti apá àríwá ilè yìí ló njá àwon Eran náà sílè.

Bíótilèjépé àwon Oníbara kò tíì pò tó béè, àmó tó jé pé, àwon tó nta óúnje Eran ní ojà won ntà wìtì wìtì.      

Wojuade/Daramola

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *