Alaga igbimo tekoto ile Asofin Apapo, foro eto eko kariaye, Ojogbon Julius Ihonvbare ti gboriyin fajo ro n risi eto eko kariaye, UBEC famojuto re lori awon ise akanse yika awon ipin.

Ojogbon Ihonvare lo siso loju oro yii lakoko to n kin aba eto isuna re leyin nile Asofin Agba.

Nigba tigbimo tekoto ile naa n fi idunu re han pelu amojuto ajo UBEC lori awon eto gbogbo to wa sninu aba wto isuna odun 2021, soo di mimo pe, oun ti setan lati sise papo pelu ajo naa nidi didaruko awon ipinle ti awon ise tiwon se nibe kudie kaato.

Ninu oro omo igbimo tekoto ile to ku, ni won tin taari oniruuru ibeere soga Agba ajo UBEC ninu eyi ti won n ti toju laifi wo ibi ti se de duro lori awon ise akanse lawon ipinle, eyi tiwon sa pejuwe re gege bi iwa aikobiarasi latodo ajo UBEC.

Won ko sai tun ke salakoso feto eko lati lo ida  kan lara owo to w anile, fun kiko awon yara iyawe kawe, nimo odi yi awon ile iwe ka ati ipese oni sawon ile-iwe gbogbo to je ti joba.

Folakemi Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *