Home Posts tagged UBEC
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Ǹgba Lérò Láti Máà Sanwó Fáwọn Akẹ́kọ Ẹ̀kọ́sẹ́ Olùkọ́

Ìjọba àpapọ̀ ti ń gba lérò láti máà san ẹgbẹ̀rún márùndínlọ́gọ́rin fún ìdajì sa ètò ẹ̀kọ́ fáwọn akẹ́kọ tó n kọ ẹ̀kọ́ ìmọ̀ olùkọ́ lọ́wọn ilé ẹ̀kọ́ ìjọba àti ẹgbẹ̀rún lọ́nà àdọ́ta fáwọn tó bá ń kẹ́kọ nílé ẹ̀kọ́sẹ́ olùkọ́ nílẹ̀ yí. Alákoso fétò ẹ̀kọ́, Ọ̀gbẹ́ni Adamu Adamu ló sọ̀rọ̀ náà lásìkò ayẹyẹ àyájọ́ ọjọ́ […]Continue Reading