Home Posts tagged Chris Ngige
Education

Strike: FG Faults ASUU’s Stance

The Minister of Labour and Employment, Senator Chris Ngige has blamed the Academic Staff Union of Universities for prolonging the strike in the country. The Minister who disclosed this in a statement issued by Acting Head of Press and Public Relations, Patience Onuobia, in the ministry said the union had made negotiation difficult for both […]Continue Reading
Yoruba

Ẹgbẹ òsìsẹ́ àti ìjọba sún ìdúnadúrà lórí owó osù síwájú

Ìpàdé lórí ẹ̀kún owó osù oní ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n tí ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ àti ìjọba gùùnlé ni ó tún ti forí sọ́pọ́n nígbàtí wọ́n ò lee fẹnu kò síbi kan lẹ́yìn wákàtí mẹ́san tí wọ́n ti ńsèpàdé. Alákoso fọ́rọ̀ àwọn òsìsẹ́ àti ìgbanisísẹ́, Dókítà Chris Ngige nígbàtí ó n bá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ nílu Abuja […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ ńgbèrò àtúngbéyẹ̀wò owó àwọn tó dipò òsèlú mú

Ìjọba àpapọ̀ ti sọ pé, kòní pẹ́ tó n yóò fi sàgbéyẹ̀wò owó osù gbogbo àwọn tó dipò òsèlú mú pátá. Ìlú Abuja lalákoso fọ́rọ̀ isẹ́ àti ìgbanisísẹ́, ọ̀mọ̀wé Chris Ngige ti sísọ lójú ọ̀rọ̀ yíì, lákokò àbẹ̀wò ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ láwọn ìjọba ìbílẹ̀. Gẹ́gẹ́ bó se wípé, ó sepàtàkì kíwọ́n sàgbéyẹ̀wò owó osù àtàwọn […]Continue Reading
Yoruba

Ìdúnadúrà láarin ìjọba àti ẹgbẹ́ òsìsẹ́ ńtẹ̀síwájú

Ìdúnadúrà tó ń wáyé láarin ìjọba àpapọ̀ àtẹgbẹ́ òsìsẹ́ lórí ọ̀rọ̀ owó osù àwọn òsìsẹ́ tókéré jùlọtún bẹ̀rẹ̀ lóni nílu Abuja. Ìpàdé náà tí wọn ò forí rẹ̀ tìsíbìkan lána niwọ́n tún gùnlé ní dédé ago méjì ọ̀sán òní. Igbákejì àarẹ ẹgbẹ́ òsìsẹ́ nílẹ̀ yíì, ọ̀gbẹ́ni Amaechi Asugunim, fi ìrètí hàn pe, ìpàdé náà yóò […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ àti ẹgbẹ́ òsìsẹ́ ńfikùnlukùn lórí owó òsìsẹ́ tuntun

Ìjọba àpapọ̀ ilẹ̀ yíì àti ẹgbẹ́ àwọn òsìsẹ́ ńfikùnlukùn láti fọ̀rọ̀jomito ọ̀rọ̀, lórí àlékún owó osù òsìsẹ́ tówà lákàsọ̀ tókéréjù ẹgbẹ̀rún lọ́nà ọgbọ̀n náirà. Ìpàdé yíì ló ń wáyé lẹ́yìn ìpàdé èyí tíwọ́n se lána òdeyi níbi tẹ́gbẹ́ àwọn òsìsẹ́ ti fi ìpinu wọn lórí àlékún náà hàn, tí ìpàdé òní sì níse pẹ̀lú ìpinu […]Continue Reading