Gomina ipinle Oyo, Onimo Ero Seyi Makinde ti salaye igbiyanju eto isakoso ijoba re lori ati koju ipenija eto aabo nipinle naa. Gomina Makinde se adayanri oro yi lasiko to n gbalejo asoju awon logaloga ileese olodun to lo fun eto idanileko eleekerinlelogoji ile eko oloogun to wa ni Jaji labe Continue Reading
Gomina Seyi Makinde tipinle Oyo ti beere fun atileyin ile ise omo ologun ile yi lawon enu aala Ipinle Oyo lati lee jeki Alafia ati aabo fese rinle. Gomina Makinde soro yi lasikko ti olori awon omo ologun ile yi, Ogagun Farouq Yahaya sabewo si lara abewo enu ise re si ekun keji ile ise […]Continue Reading
Awon Asofin Egbe Oselu PDP To N Soju Ipinle Oyo Nile Asofin Apapo Seleri Atileyin Fun Gomina Makinde
Gomina Ipinle Oyo, Onimo ero Seyi Makinde ti soo di mimo wi pe ijoba re ti n sapa lati fi ri daju pe idagbasoke to nitumo jeyo nidi igbiyanju ati wagbo dekun fun eto aabo to mehe nipinle Oyo. O sipaya oro yi lasiko ti awon omo ile igbimo asofin ile yi ti won n […]Continue Reading
Gomina Ipinle Oyo, Onimo ero Seyi Makinde tip e awon oloye tuntun egbe oselu PDP fekun guusu iwoorun ile yi nija pe ki won rii daju pe ajosepo to danmoran wa laarin awon omo egbe to n fi apa janu. O soro yi lasiko eto ibura fun awon oloye tuntun naa nile egbe oselu PDP […]Continue Reading
Ijoba Ipinle Oyo ti pese owo iwuri oju ese fawon iko elere idaraya ton soju ipinle Oyo ti won ti gba ami eye nibi idije ere idaraya ile yi ton lo lowo nipinle edo. Nigba ton fun won ni owo naa nibudo ti won pago si nile eko giga Fasiti Benin Alaga Ajo Elere Idaraya […]Continue Reading
Gomina Ipinle Oyo, Onimo ero Seyi Makinde so pe gbogbo eto ti isejoba re la kale lo tin lo lowo lati mu ki papako ofurufu ilu ‘Badan di eyi ti gbogbo eeyan lekun yi joma lo. O siso loju oro yi, lasiko ti ogaagba ileese Ologun Ofurufu, Air Vice Marshal Olaonipekunn Makinde se abewo ekuse […]Continue Reading
Gomina ipinle oyo, onimo ero seyi makinde ti so pe isejoba re, yo tesiwaju lati ma fi awon liana lele ti yo mu keto oro aje gboro si nipinle yi. O soro yi lasiko, ton forowero pelu awon asaju ninu oja ati pelu awon egbe onise owo yika ipinle oyo, eyito waye nilijoba to wa […]Continue Reading
Ni ipalemo fun eko idibo si awon ijoba ibile nipinle Oyo, Gomina Seyi Makinde ti sefilole igbimo ti yio sagbeyewo bi awon adale alaga ti se sise kun oju osuwon si ni awon ijoba ibile meteetalegbon. Ifilole igbimo naa to waye nile ijoba to wa ni Agodi nilu Ibadan. Gomina Makinde ni igbimo naa gbodo […]Continue Reading