-
Àarẹ Buhari kí ikọ̀ Super Falcons kú oríìre àseyọrí wọn nínú ìdíje WAFCON
Àarẹ Muhammadu Buhari ti kí ikọ̀ agbágbbọ̀ọ̀lù Super Falcons kú oríìre àseyọrí wọn nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ wọn pẹ̀lú ikọ̀ Indomitable Lioness ti Cameroon pẹ̀lú àmì ayò kan sí òdo nínú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀ ìpele kejì tó kángun sí àsekágbá níbi ìdíje ife ẹ̀yẹ ilẹ̀ adúláwọ̀ tàwọn Obìnrin tọdún 2022 tó ńlọ ní Morocco. Àtẹ̀jáde látọ̀dọ̀ amúgbálẹ́gbẹ àarẹ lórí…