Home Posts tagged ìjàmbá ọkọ̀
News Yoruba

Àjọ ẹ̀sọ́ ojú pópó kọminú lórí bí ìsẹ̀lẹ̀ ìjàmbá ọkọ̀ se ń pelékesi.

Olùdarí àjọ ẹ̀sọ́ ojú pópó nílẹ̀ yíì, FRSC, ẹ̀ka nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, arábìnrin Uche Chukwurah sọ pé, àkọsílẹ̀ àwọn ìjàmbá ọkọ̀ ojú pópó tajọ náà se láàrin osù keje sósù kẹsan ọdún yíì, ti pọ̀jù, èyí tó se nígbà tí ọdún yíì dá sí méjì lọ, tí se méjìléladọfa. Arábìnrin Chukwurah tó sọ̀rọ̀ yíì di Continue Reading