Ijoba Ipinle Ekiti ti sun ofin kon le o gbele oni wakati meranlelogun to bere lele lojo isegun nipinle naa sinawju si. Akowe iroyin fun Gomina, Ogbeni Yinka Oyebode lo kede oro yi ninnu atejade to fi sita nilu Ado-Ekiti pelu alaye wipe ofin kon le o gbele naa lo sin tesiwaju di ojo miin Continue Reading
Igbimo Alase Ijoba Ipinle Ekiti ti fowosi iyansipo Omooba Ajakaye Adeola Adeniyi gege bi Oluyin ti Iyin Ekiti nijoba ibile Irepodun/Ifelodun nipinle naa. Igbese iyansipo naa niwon fowosi nibi ipade pataki igbimo Alase ofun, eleketadinlogun ire re, eyi ti Gomina Kayode Fayemi lewaju fun. Alakoso feto Iroyin atilaniloye araaly, nipinle naa, Ogbeni Akin Omole lo […]Continue Reading