Yoruba

Ofin Kon le O Gbele si N Tesiwaju Nipinle Ekiti Di Ojo Miin Ojo Re

Ijoba Ipinle Ekiti ti sun ofin kon le o gbele oni wakati meranlelogun to bere lele lojo isegun nipinle naa sinawju si.

 Akowe iroyin fun Gomina, Ogbeni Yinka Oyebode lo kede oro yi ninnu atejade to fi sita nilu Ado-Ekiti pelu alaye wipe ofin kon le o gbele naa lo sin tesiwaju di ojo miin ojoo re.

 O fi emi ope han si gbogbo eeyan ilu naa fun ifowosowopo won, pelu fifowo soya pe alaafia yoo joba pada nipinle naa laipe ojo.

 Babatunde

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *