Yoruba

Ile Igbimo Asofin Da Laba Lati Da Eto Ikaniyan Fun Todun 2021 Duro Die Naa

Ile igbimo asofin ti ro ijoba apapo lati da igbese eto ikaniyan to ye ko waye ninu odun 2021, tawayi duro, eyi ti ajo to n kaniyan nile NPC yi ngbero lati dawole duro naa nitori eto ebo to mehe.

Asofin kan, Ogbeni Shehu Beji, lo daba yi, lasiko ijoko ile, to si koroju si, ipo ti mehe teto abo w anile yi, to ti so opo da lainile lori mo lawon agbegbe kokan.

Ogbeni Beji eni to so pe opo awon ti ko nile lori mo ni won ti lo sawon orileede to mule tile yi, lati lo satipo, ti won ko si ni lanfani lati je kika, o fun sope eto ikaniyan lasiko teto oro ahe denukole yi loun kasi fifi nkan ini sofo.

Asofin ohun fikun pe, gbigbe awon osise feto ikaniyan lo sawon agbegbe teto abo ti mehe, ni yoo dabi pe won kan fe fie mi won tafala lasan ni.

Sherifdeen/Wojuade 

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *