Home Posts tagged Johẹsu
News Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ ti késí ẹ̀ka àjọètò-ìlera, Johẹsu láti sẹ̀wẹ̀lé ìyansẹ́lódì tíwọ́n gùnlé jákè-jádò ilẹ̀ yíì.

Alákoko fétò ìlera, Díkítà Osagie Ehanire, ẹnito sọ̀rọ̀ yíì níbi àbò ikọ̀ amúsẹ́yá ìjọba àpapọ̀ fárùn covid-19, nílu Abuja rọ àwọn òsìsẹ́ ọhun láti sọ àsọyépọ̀ pẹ̀lú àwọn tọ́rọkàn. Alákoko sọ̀rọ̀ yíì wákàtí diẹ lẹ́yìn táàrẹ, àjọ Johesu, Dókítà Biobelomoye Josiah, rọ ìjọba àpapọ̀ láti dáhùn àwọn Continue Reading