Home Posts tagged Senator Ahmed Lawan
Yoruba

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin àgbà setán láti sàtúngbéyẹ̀wò òfin ilé gbe ìjọba àpapọ̀

Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin àgbà ilẹ̀ yíì, ọ̀mọ̀wé Ahmed Lawan sọpé ilé ti setán láti sàtúngbéyẹ̀wò òfin tó síse pẹ̀lú ilégbe ìjọba àpapọ̀ láti mú ìdúró réè bá ẹ̀ka náà kíì ìfẹsẹ̀múlẹ̀ tílẹ̀lé ìlànà yíì fáwọn ilésẹ́ aládani jẹ́ títẹ̀lé sansan. Ọmọwe Lawan sọ èyí lásìkò tíì olùdarí ilésẹ́ tó ńrísí ilégbe ìjọba àpapọ̀, ọ̀gbẹ́ni […]Continue Reading
Yoruba

Asòfin dába atungbeyewo àte ètò ẹ̀kọ́

Olórí ilé ìgbìmò asofin nílè yíì Senato Almad Lawan ti késí àwọn olùdarí ilé ìwé lorileèdè yi láti sátúngbeyẹ̀wò àte ètò ẹ̀kọ́ ní gbogbo ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ nílè yi. Senato Lawan dába ọ̀rọ̀ yi nígbàtí ó nside ìjóko gbogbogbo lórí Ijíròrò lórí àbá òfin tí wọ́n fẹ́ fi ṣàgbékale àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga ìjọba àpapọ̀. […]Continue Reading
Yoruba

Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin ilẹ̀ yìí pè fún àdúrà sí ojútu sí àwọn ìsòro

Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin àgbà ilẹ̀ yíì Sẹ́nátọ̀ Ahmed Lawan, sopé orílẹ̀èdè Náijírìa nílò àdúrà kólè boorí àwọn ìpèníjà rẹ̀. Sẹ́nátọ̀ Lawan sọ èyí nígbà tó ńgba àwọn asòfin tójẹ́ ọmọ lẹ́yìn Krístì lálejò. Ẹgbẹ́ àwọn asòfin tó jẹ́ ọmọ lẹ́yìn Krítì ọ̀hún ní igbákejì adarí ilé Sẹ́nátọ̀ Ovie ọmọ-Agege àti akójanu ilé Sẹ́nátọ̀ Orji […]Continue Reading