Yoruba

Ilésẹ́ ọlọ́pa fọwọ ìdánilójú sí sisẹ́ wọn bísẹ́ sọya lákoko ètò ìdìbò ìpínlẹ́ẹ̀ Edo àti Ondo.

Ọga àgbà ilésẹ̀ ọlọ́pa lórílẹ̀èdè yíì, Muhammed Adamu ti fọwọ́ ìdánilójú sọ̀yà fáwọn èèyàn ilẹ̀ yíì, pé, ilésẹ́ ọlọ́pa kòní sègbè tàbí yapa sófin nídi fífẹsẹ̀ òfin múlẹ̀ nínú ètò ìdìbò sípò Gómìnà tó ńbọ̀ nípinlẹ̀ Edo àti Òndó.

Ọga àgbà ọ̀hún sọ èyí, lásìkò ìpàdé rẹ̀ pẹ̀lú àwọn àjọ tó ńrísí, fífẹsẹ̀ ètò ìdìbò tí o lẹ́ja-nbákan nínú nílu Abujam sèlérí pé ilésẹ́ ọlọ́pa yóò sàmúlò gbogbo ọ̀nà láti fẹsẹ̀ ètò ìdìbò tóòdúró réè múlẹ̀.

Ọgbẹni Adamu sọpé, ìgbésẹ̀ tí ńjẹ́ gbígbé láti fẹsẹ̀ àláfìa múlẹ̀ láwọn ìpínlẹ̀ méjèjì láti dènà rògbòdìyàn yóòwu tólè fẹ́ẹ̀ súyọ.

Elizbeth Idogbe

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *