Yoruba

Ajo NECO Se Atunse Ate Idanwo

Ajo to n seto idanwo NECO ti se atunse si ate eto idanwo naa to yeko waye lojo kijilelogun, iketalelogun ati ikerinlelogun osu yi si osu kokanla nitori rogodiyan ati ofin konle o gbele to n waye lawon ipinle kan.

 Oga agba leka eti iroyin fun ajo NECO, Ogbeni Azeez Sani lo kede oro yi ninu atejade to fi sita fawon oniroyin nilu Abuja.

 Ogbeni Sani soo di mimo pe won ti sun awon idanwo naa si ojo ketadinlogun, ikejidinlogun ati ikokandinlogun osu kokanla.

  O tenumo pe igbese naa nira fun ajo naa nipa bi won yoo se tun ko iwe idanwo miin sowo si gbogbo orileede yi.

 Salaudeen

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *