Àjọ tó ń rísí ipeniye ohun tẹ́nu ń jẹ àti mimu pẹ̀lú egboogi lórílẹ̀èdè yí, NAFDAC, ti se ìfilọ́lẹ̀ tí kò pe níye, ǹkan ìpara tó léwu, omi inu ọrọ ti kò peye àti àwọn ǹkan ilo gbogbo tó kù diẹ káàto. Olùdarí àgbà àjọ NAFDAC, ọ̀jọ̀gbọ́n Mojisọla Adeyẹye ló se ìkìlọ̀ yí lásìkò tó […]Continue Reading