Home Posts tagged Commissioners
Yoruba

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Èkìtì, buwọlu orúkọ àwọn méje tójẹ́ fífí sọwọ́ gẹ́ẹ̀gẹ́ bí alákoso

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Èkìtì tí bowọlu àwọn alákoso méje tí Gómìnà Kayọde Fayẹmi fi sọwọ́ sílé láipẹ yíì. Lásìkò ètò náà, diẹ lára àwọn asòfin lára èyí tarirí igbákejì adarí ilé, ọ̀gbẹ́ni Akeem Jamiu àti ọ̀gbẹ́ni Aribasoye láti ẹkùn ìdìbò Ìkọ̀lé kiní, bere ọ̀kan-òjọ̀kan ìbere lọ́wọ́ àwọn alákoso tíwọ́n forúkọ wọn sọwọ́ ọ̀hún lórí […]Continue Reading