Home Posts tagged NSCDC Oyo Command
Yoruba

Àwọn ikọ̀ alábo pawọ́pọ̀ láti wójùtú sí ètò àbò tó mẹ́hẹ nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́

Ilé isẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́ àti àjọ ọ̀tẹlẹ̀múyẹ́, DSS, ti tẹnumọ́ ìpinu wọn láti fọwọ́sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àjọ áàbò araẹni láàbò ìlú, NSCDC, láti wá ojútu sí ìsoro ọ̀rọ̀ ààbò àti àwọn ìwà ọ̀daràn nípinlẹ̀ yí. Ọga àgbà ilé isẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́ arábìnrin Ngozi Ọnadẹkọ àti akẹgbẹ́ rẹ̀ ọ̀gá àjọ Continue Reading
News Yoruba

Àjọ àbò ara ẹni làbòlú ńfẹ́ kí àjọsepọ̀ kó wà lárin gbogbo ilésẹ́ alábo gbogbo

.Àjọ àbò ara ẹni lábòú, ńfẹ́ kíì àjọsepọ̀ tó lóòrin kówà lárin gbogbo ilésẹ́ elétò àbò gbogbo, láti lè sisẹ́ papọ̀ wójùtú sí ètò àbò tó mẹ́hẹ nílẹ̀ yí. Ọgagba àjọọ̀hún tuntun nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbẹ́ni Micheal Adaralẹwa ló sọ̀rọ̀ yí lásìkò àbẹ̀wò ẹnusẹ́ sí ọ̀gágba tó ń sànkóso ọgbà ẹ̀wọ̀n. Ọgbẹni Adaralẹwa, tẹnumọ́ pé ìbásepọ̀ […]Continue Reading
Yoruba

Ọdún Àjínde: Àjọ NSCDC Kó Àwọn Òsìsẹ́ Rẹ̀ Tó Lé Lẹ́gbẹ̀rún Méjì Síta

Àjọ ààbò ara ẹni láàbò ìlú, NSCDC, nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti kó àwọn òsìsẹ́ rẹ̀ tó tó ẹgbẹ̀rún méjì àbọ̀ ló si tibu tóòro ìpínlẹ̀ yi láti ríì dájú pé kò sí àayè fún ìwà ọ̀daràn lásìkò pọ̀pọ̀sìnsìn ọdún ajinde. Àtẹ̀jáde ti agbẹnusọ àjọ náà nípinlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ọ̀gbẹ́ni Oluwọle Olusẹgun fi síta nílu Ìbàdàn sọ wípé […]Continue Reading
Crime

Soldier Crushed by Runaway Truck in Ibadan

A military officer attached to Joint Task Force, Igbeti in Oyo State and identified as “Uthman Muhammed” has been crushed to death by a runaway trailer. The accident occurred on the new Ibadan-Oyo expressway, Powerline, Moniya, Ibadan on Sunday afternoon. A witness of the incident, Mr Ayotunde Ojo explained that the accident happened as a […]Continue Reading
Security

NSCDC Oyo Gets New Commandant

Nigeria Security and Civil Defence Corps, NSCDC, Oyo state command has gotten a new Commandant. He is Mr. Iskilu Akinsanya. Before the new appointment, Mr. Akinsanya was the Commandant in charge of logistics at the headquarters, Abuja. Mr. Akinsanya has taken over the mantle of leadership from the former Commandant, Dr John Adewoye who has […]Continue Reading