.Àjọ àbò ara ẹni lábòú, ńfẹ́ kíì àjọsepọ̀ tó lóòrin kówà lárin gbogbo ilésẹ́ elétò àbò gbogbo, láti lè sisẹ́ papọ̀ wójùtú sí ètò àbò tó mẹ́hẹ nílẹ̀ yí.

Ọgagba àjọọ̀hún tuntun nípinlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbẹ́ni Micheal Adaralẹwa ló sọ̀rọ̀ yí lásìkò àbẹ̀wò ẹnusẹ́ sí ọ̀gágba tó ń sànkóso ọgbà ẹ̀wọ̀n.

Ọgbẹni Adaralẹwa, tẹnumọ́ pé ìbásepọ̀ yi nìkan ló lè fòpin sí ìwà ọ́daràn láwùjọ tálafìa yo si jọ ba.

Ó sọ síwájú pé, àjọ àbò ara ẹni lábòlú ni kòní fàyègba, jiji dukia arálu, ìjínigbé àtàwọn ìwà ìbàjẹ́ miran láwùjọ lábẹ́ ìsàkóso rẹ̀.

Ọgagba ọgbà ẹ̀wọ̀n, ọ̀gbẹ́ni Ailewọn Noel sọ pé yàtọ̀ fún àjọsepọ̀ yio dara tawo òsìsẹ́ alábo bánlo irinsẹ́ ìjagun wọn láti dábòbò ẹ̀mí àti dúkia arálu dípò fún kíwọ́n ma lo fi dún kokò mọ́ ni láwùjọ.

Makinde/Afọnja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *