Home Posts tagged NUT
Yoruba

NUT bèrè fún ohun amáyédẹrùn fétò ẹ̀kọ́ tóyèkóòro

Ẹwẹ wọ́n ti rọ ìjọba láti pèsè àwọn ohun amáyédẹrùn tóòyẹ sáwọn ilé-ìwé kétò ẹ̀kọ́ kíkọ́ léè rọrùn. Alága ẹgbẹ́ àwọn olùkọ́ nílẹ̀ yíì NUT, ẹ̀ka tìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, ọ̀gbẹ́ni Samson Adedoyin sọ̀rọ̀ yíì lásìkò tó ńbá akọ̀ròyìn ilésẹ́ wa sọ̀rọ̀ lórí àyájọ́ ọjọ́ olùkọ́ fún tọdún yíì. Alága ẹgbẹ́ NUT, ohun Continue Reading