Home Posts tagged Covid-19 (Page 2)
Health

BREAKING: Security Operatives Bar Unvaccinated Civil Servants From Federal Secretariat, Abuja

Civil servants and the general public without proof of vaccination and negative PCR tests are currently being prevented from accessing government buildings in Abuja. The PUNCH had reported that the Boss Mustapha-led presidential steering committee on COVID-19 had announced in October that civil servants without proof of vaccination and negative PCR tests would not be […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Sèkìlọ̀ Fáwọn Òsìsẹ́ Lórí Abẹ́rẹ́ Àjẹsára Covid-19

Sáàjú gbèdéke ọjọ́ kini osù kejìlá, fún gbígba abẹ́rẹ́ àjẹsára àrùn Covid-19 fáwọn òsìsẹ́ ìjọba, ìjọba àpapọ̀ ti sèkìlọ̀ fáwọn òsìsẹ́ tó fẹran isẹ́ wọn láti lọ gba abẹ́rẹ́ àjẹsára. Pẹ̀lú onírunru ẹrọ tón tẹlẹ ọ̀rọ̀ yíì, èyító jẹ́ kíkéde lósù kẹsan, ìjọba ni ìgbésẹ̀ náà wáàyé níbamu pẹ̀lú ifẹ̀ àwọn èèyàn ilẹ̀ Nàojírìa. Nígbà […]Continue Reading
Health

3rd Wave: 80% Of Death Casualties Were Not Vaccinated – Oyo Covid-19 EOC

The chances of death of Covid-19 unvaccinated people is four times higher than people who are fully vaccinated against the disease. Co-lead, Oyo State Covid-19 Emergency Operation Centre, Doctor Fisayo Oluwatosin made this known while featuring on straight talk, an interview programme on Premier FM. Doctor Oluwatosin who highlighted the importance of Covid 19 vaccination, Continue Reading
Yoruba

Ìjọba Àpapọ̀ Fẹ́ Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Lórí Fífòpinsí Lásigbo Akọ-Sákọ Àti Abo-Sábo

Igbákejì olórí orílẹ̀èdè yí, ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmi Ọsinbajo, ti fìdùnú rẹ hàn sí bí ìwà lásígbo akọsákọ òhun abosábo se ń díkùn nípasẹ̀ ìdásí àwọn asáàjú àwùjọ àtàwọn olórí ẹlẹ́sìnjẹsin nílẹ̀yí. Ó sọ̀rọ̀ náà nílu Abuja lásìkò tó ń sọ̀rọ̀ níbi è[tò kan tó wáyé. Ọjọgbọn Ọsinbajo tí alákoso fọ́rọ̀ àwọn obìnrin, Dame Pauline Tallen sojú […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ògùn Gùnlé Ìlanilọ́yẹ̀ Lórí Ẹ̀yà Àrùn Covid-19 Min

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn ti gùnlé ìlanilọ́yẹ̀ lórí àyẹ̀wò láwọn ìjọba ìbílẹ̀ márun tí àrùn covid-19 ti nwopo pẹ̀lú àmọ̀nràn fáwọn olùgbé ibẹ̀ láti ríì dájú wípé wọn tẹ̀lé ìlànà ìlera lọ́nà àti dáàbòbò ara wọn lórí ẹ̀yà TUNTUN ÀRÙN COVID-19 tí a mọ̀ si Delta. Alákoso fọ́rọ̀ ìlera nípinlẹ̀ Ògùn, Dókítà Tomi Coker ló sọ̀rọ̀ […]Continue Reading