Home Posts tagged Babajide Sanwo-Olu
Politics

Sanwo-Olu Wins Lagos APC Governorship Ticket

Governor Babajide Sanwo-olu has been  declared winner of the Lagos State APC Governorship Primary Election with  1,117 votes. The Governor was the only aspirant cleared for the party election which was held at Mobolaji Johnson Arena Onikan, amidst tight security under the watch of the officials of the Independent National Electoral Commission. Voting by delegates […]Continue Reading
Politics

Southern Governors Advocate Power Shift

Governors from the Southern part of the country, under the aegis of the Southern Governors Forum, have canvassed a rotational Presidency between Northern and Southern Nigeria, with a resolve that the next President must emerge from the South. In order to consolidate democracy and strengthen the Electoral process in the Country, the Southern Governors’ Forum […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ èkó sèlérí pé isẹ́ àkànse kíkọ́ òpópónà apapa yo parí nínú ọdún yí

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti sọpé gbogbo òpópónà àti afárá èyí tí wọ́n ńkọ́ lọ́wọ́ ládugbò Apapa ni yo jẹ píparí nínú osù kẹwa ọdún tawàyí. Gómìnà Babajide Sanwo-olu ló sọ̀rọ̀ ìdánilójú yi lásìkò tó se àbẹ̀wò láti mọ ibi tísẹ́ dé dúró lágbègbè náà, n’ípinlẹ̀ Èkó. Gómìnà Sanwo-olu, sọpé súnkẹrẹ f’àkẹrẹ ọkọ̀, tón f’ojúmọ́ faye […]Continue Reading
Yoruba

Gómìnà Sanwoolu sèrànwọ́ owó fún àwọn tó lùgbàdì ìjànbá ìbúgbàmù nílu Èkó

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, ọ̀gbẹ́ni Babajide Sanwolu ti ya owó bí Bíllìọnù méjì naira sọ́tọ̀ gẹ́gẹ́ bí owó gbà mábinú fáwọn èèyàn tólùgbàdì ìsẹ̀lẹ̀ ìbúgbàmù tó wáyé nípinlẹ̀ náà. Ìpínlẹ̀ Èkó ni Gómìnà Sanwoolu ti fìdí èyí múlẹ̀. Gómìnà Sanwo-olu ẹnití, igbákejì rẹ̀, ọ̀mọ̀wé Fẹmi Hamzat kọ́wọrìn pẹ̀lú báwọn tólùgbàdì ìsẹ̀lẹ̀ náà kẹ́dùn tófimọ ẹbí àwọn […]Continue Reading
Yoruba

Gọ́mìnà Sanwoolu pàsẹ atúnse òpópónà jákèjádò ìpínlẹ̀ Èkó

Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkó, Ọ̀gbẹ́ni Babajide Sanwoolu ti pàsẹ pé kí wọ́n lọ bẹ̀rẹ̀ àtúnse àwọn ọ̀nà tó ti bàjẹ́ gidi gan, àtàwọn pópónà ńlá ńlá nígboro ìpínlẹ̀ nà, bẹ̀rẹ̀ látòní lọ. Sanwoolu pàsẹ yi, lẹ́yìn tó ti sèpàdé pẹ̀lú iléésẹ́ onímọ̀-ẹ̀rọ mẹ́jọ kan tí wọ́n ní wọ́n ó gbé isẹ́ nà fun. Bákanà ni Gómìnà […]Continue Reading
Yoruba

Gómìnà Sanwoolu gbàmọ̀ràn lórí ìfọkànsì

Gómìnà Babajide Sanwo-Olu gbàwọn ọmọ orílẹ̀dè yíì níyànjú láti nígbàgbọ́ kíwọ́n sì fìmọ̀sọkan, pé ilẹ̀ yíì sì máà dára. Gómìnà Sanwo-Olu tún kọminú lórí báwọn ọmọ orílẹ̀dè yíì kan se ńsíkúrò nílẹ̀ yíì, lọ sí ilẹ̀ òkèrè níbi tílẹ̀ tó ń mú kílẹ̀ Nàijírìa pàdánù àwọn ọlọ́pọlọ pípé ẹ̀dá, tíwọ́n lè mú ìdàgbàsókò bá orílẹ̀dè. […]Continue Reading