September 21, 2020
Yoruba

Gómìnà Sanwoolu sèrànwọ́ owó fún àwọn tó lùgbàdì ìjànbá ìbúgbàmù nílu Èkó

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Èkó, ọ̀gbẹ́ni Babajide Sanwolu ti ya owó bí Bíllìọnù méjì naira sọ́tọ̀ gẹ́gẹ́ bí owó gbà mábinú fáwọn èèyàn tólùgbàdì ìsẹ̀lẹ̀ ìbúgbàmù tó wáyé nípinlẹ̀ náà.

Ìpínlẹ̀ Èkó ni Gómìnà Sanwoolu ti fìdí èyí múlẹ̀.

Gómìnà Sanwo-olu ẹnití, igbákejì rẹ̀, ọ̀mọ̀wé Fẹmi Hamzat kọ́wọrìn pẹ̀lú báwọn tólùgbàdì ìsẹ̀lẹ̀ náà kẹ́dùn tófimọ ẹbí àwọn èèyàn tó sọ ẹni wọn nù àtàwọn dúkia wọn bààná sínú ìsẹ̀lẹ̀ ọ̀hún.

Yẹmisi Dada/Kẹmi Ogunkọla

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *