Home Posts tagged #EndSARS
Security

#ENDSARS: Victim Calls for Help

A victim of Endsars protests, Ajani Toheeb, has appealed to the Oyo State Judicial Panel of Inquiry on Police brutality,  to order the Nigeria Police to be responsible for his hospital bill.  In a petition against Nigeria Police Ojoo Police Station, Ibadan, Toheeb said he was hit by the Police bullet at Ohio while supplying smoked […]Continue Reading
Yoruba

Ọga Ọlọ́pa Pátápátá Ti Rọ Àwọn Ọlọ́pa Láti Padà Sẹ́nu Isẹ́ Wọn

Ọga àgbà yányán fún ilésẹ́ ọlọ́pa orílẹ̀èdè yíì, Ọ̀gbẹ́ni Muhammed Adamu ti rọ àwọn ọlọ́pa láti máse kárẹ ọkàn nídi isẹ́ tí wọ́n yàn láayo. Ó sọ̀rọ̀ yíì lásìkò tó ńbá àwọn òsìsẹ́ ọlọ́pa nípinlẹ̀ Ògùn sọ̀rọ̀ lólú ilésẹ́ náà eléwéran nílu Abẹokuta lásìkò àbẹ̀wò rẹ̀ sáwọn ìpínlẹ̀ ìwọ̀-oorùn orílẹ̀èdè yíì. Ọ̀gbẹ́ni Adamu sàlàyé pé, […]Continue Reading
Yoruba

Gómìnà Seyi Makinde Sèlérí Láti Mú Inú Ẹbí Àwọn Ọlọ́pa Tíwọ́n Sekúpa Nínú Ìfẹ̀húnúhàn Dùn

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Onímọ̀ẹ̀rọ Seyi Makinde ti sèlérí pé òun yóò ridájú pé òun dun ẹbí àwọn ọlọ́pa tíwọ́n sekúpa lákokò ìfẹ̀húnúhàn fífòpinsí ikọ̀ SARS, nínú tóun yóò sì sàtúnse sáwọn ilé-isẹ́ ọlọ́pa tíwọ́n bà jẹ́. Níbi ìpàdé àláfìa kan tí Gómìnà se pẹ̀láwọn ọ̀gá àgbà ilé-isẹ́ ọlọ́pa ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tó wáyé lólúlesẹ́ náà, ládugbò […]Continue Reading