Yoruba

Iku ogbontarigi onilu apala Alhaji Abdulrahman Alao Adewole ni won ti se àpèjúwe re gege bi eyi to fopin si awon iran kan ninu orin apala.

Isinku olori egbe apala Ayinla Omowura nile re nilu Abeokuta ni awon ogunlọgọ eniyan peju pese si.

Akoroyin wa Wale Oluokun jabo wipe odekan gbogii ti onilu agba naa lo kẹhìn ni ayẹyẹ odun ilu ti Ijoba ipinle Ogun se agbateru re nilu Abeokuta.

blob:https://radionigeriaibadan.gov.ng/542a9056-2c99-4bcf-b04a-82c6742ae8b0
Entertainment

The death of the lead Apala music drummer, Alhaji Abdulrahman Alao Adewole has been described as the end of an era in Apala music genre.

The burial rite of the leader of Ayinla Omowura Apala music group at his residence in Abeokuta had hundreds of music lovers in attendance.

Correspondent Wale Oluokun reports that the last major outing of the talking drum specialist was the last African Drum festival hosted by the Ogun State Government in Abeokuta.

blob:https://radionigeriaibadan.gov.ng/ae008d29-a3c1-4e36-b6a5-3067a69f850f