Home Posts tagged Àwọn èyàn tóní ìpèníjà ara
Yoruba

TESCOM: Àwọn èyàn tóní ìpèníjà ara ńfẹ̀húnúhàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́

Lóòrọ̀ òní, àwọn òsìsẹ́ ọba ni kò rọrùn fún láti wọ ilésẹ́ ìjọba ní Secretariat, Agodi ìbàdàn, lẹ́yìn tí àwọn tó ní ìpèníjà ara ńfẹ̀húnúhàn lórí ẹ̀sùn pé ìjọba dẹ́yẹ sí wọn. Akọ̀ròyìn ilésẹ́ Radio Nigeria jábọ̀ pé àwọn àkàndá ẹ̀dá yi ni wọ́n ńgbé oníruru àkọlé lọ́wọ́ láti fi ẹ̀húnúhàn wọn hàn. Continue Reading