Home Posts tagged Best Ogedengbe
Yoruba

Ẹbí ògbóntagì agbábọlu Best Ogendegbe se rántí ẹ̀ pẹ̀lú ìfẹsẹ̀wọnsẹ̀

Lọ́jọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n osù yi ni àsekágbá ìdíje Best Ogedengbe láarin àwọn ogbábọ̀ọ̀lù tọ́jọ́ orí wọn kò kọjá ọdún mẹ́ẹ́dọgbọn  wáyé. Àwọn agbábọ̀ọ̀lù Adelagun Memorial Grammar School, Odinjo nílu Ìbàdàn àti Precing Footbal Academy, Ìdí-Ayùnrẹ́ ni yo gba ìdíje àsekágbá na. Ìdíje náà ló bọ́ Continue Reading